Song: Olorun mi, modupe}2ce
Alagbara, Alagbara to saanu mi,
Olorun mi modupe.
- By the covenant that established this mountain of mercy, let my prayers on this mount be answered by fire, in Jesus’ name
- Inu iyara ogun ti aye ti mi mo, Olorun ori Oke Aanu, mumi jade, ni oruko Jesu.
- The key of my glory stolen by wicked powers, O God arise and restore it to me now in Jesus’ name.
- Gbogbo agbara ti o n fi aye ponmi loju, e segbe, e poora loruko Jesu.
- Enikeni ti o n fowo so aya wipe Olorun ko to mi gba, ki ile to mo, Oluwa jeki ara wo ile e, ni oruko Jesu
- Ohunkohun to mumi gori oke yi, Oluwa gbe le mi lowo, ni oruko Jesu
- Oluwa o, ra igba mi pada, ni oruko Jesu
- Olorun ori oke aanu, se mi lore ti o se gbe pamo, ni oruko Jesu
- Emi ile baba mi, jade ni aye mi, loruko Jesu.
- Arrows that abort glory, I am not your candidate, therefore, come out with all your roots from my foundation, in Jesus’ name.
Help M̶̲̅ε̲̣̣̣̥ in prayer for ♏γ̲̣̣̥ marriage to work out, ♏γ̲̣̣̥ fiance steven keep talkin abt gettin married to M̶̲̅ε̲̣̣̣̥ and having children , but I dnt know what is causing the delay, I have been prayin since 3yrs for our marriage to come to reality but I dnt know why its hasn’t come to pass, pls help M̶̲̅ε̲̣̣̣̥ in prayer , iam faith ehigiamusoe ♏γ̲̣̣̥ fiance name is steven ojamiren