CONFESSION: (PSALM 118:17): I shall not die, but live, and declare the works of the LORD.
- I bind every spirit of Balaam, in the name of Jesus.
- I smash all demonic mirrors assigned against my life, in the name of Jesus.
- I shall not die young, I shall reach my full age, in the name of Jesus.
- I reject every demonic nickname, in the name of Jesus.
- My blood, be anointed with the power of the Holy Spirit, in the name of Jesus.
- Every instrument of bewitchment, be roasted, in the name of Jesus.
- Every evil plant in my life, be uprooted, in the name of Jesus.
YORUBA VERSION:
IJEWO: ORIN DAFIDI 118:17
- Mo de gbogbo emi ti Balamu, ni oruko Jesu.
- Mo fo gbogbo digi okunkun ti won yan lodi si aye mi, ni oruko Jesu.
- Emi ki yo ku ni rewerewe – Emi yo mu ojo aye mi pe, ni oruko Jesu.
- Mo ko gbogbo inagije okunkun, ni oruko Jesu.
- Eje mi gba ifororoyan nipa agbara ti Emi Mimo, ni oruko Jesu.
- Gbogbo ohun elo ti ibode, gbana, ni oruko Jesu.
- Gbogbo irugbin ibi ninu aye mi, ma fatu, ni oruko Jesu.
IGBO VERSION
NKWUPUTA: Abu Oma 118: 17
- Ekee m mmuo Balaam obula agbu, n’aha Jisos.
- Akurie m ugegbe ekwensu niile nke e zipuru imegide ndu m, n’aha Jisos.
- Agaghi m anwu na ntorobia, aga m ano kaa nka, n’aha Jisos.
- Aju m aha otutu ekwensu obula, n’aha Jisos.
- Obara m, ka e jiri ike Mmuo Nso tee gi mmanu, n’aha Jisos.
- Ihe obula nke e ji ata amusu, ka agbaa gi oku, n’aha Jisos.
- Osisi ojoo obula nke a kunyere na ndu m, ka e ropu gi, n’aha Jisos!
I LOVE THE MINISTRY OF DR. OLUKOYA. I AM BLESSED THROUGH THE PRAYER POINTS